Jeremáyà 5:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Wọ́n dà bí àwọn ẹṣin tí ara wọn ti wà lọ́nà láti gùn,Kálukú wọn ń yán sí aya ọmọnìkejì rẹ̀.*+