Sáàmù 10:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Jèhófà ni Ọba títí láé àti láéláé.+ Àwọn orílẹ̀-èdè ti ṣègbé kúrò láyé.+ Dáníẹ́lì 4:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ẹ wo bí àwọn iṣẹ́ àmì rẹ̀ ṣe tóbi tó àti bí àwọn iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ ṣe lágbára tó! Ìjọba tó wà títí láé ni ìjọba rẹ̀, àkóso rẹ̀ sì wà láti ìran dé ìran.+
3 Ẹ wo bí àwọn iṣẹ́ àmì rẹ̀ ṣe tóbi tó àti bí àwọn iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ ṣe lágbára tó! Ìjọba tó wà títí láé ni ìjọba rẹ̀, àkóso rẹ̀ sì wà láti ìran dé ìran.+