Àìsáyà 13:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ọ̀rọ̀ ìkéde sí Bábílónì,+ tí Àìsáyà+ ọmọ Émọ́ọ̀sì rí nínú ìran: Àìsáyà 13:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìdí nìyẹn tí gbogbo ọwọ́ fi máa rọ,Tí ìbẹ̀rù sì máa mú kí ọkàn gbogbo èèyàn domi.+