-
Dáníẹ́lì 4:8, 9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Nígbẹ̀yìn-gbẹ́yín, Dáníẹ́lì wá síwájú mi, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Bẹtiṣásárì,+ látinú orúkọ ọlọ́run mi,+ ẹni tí ẹ̀mí àwọn ọlọ́run mímọ́ + wà nínú rẹ̀, mo sì rọ́ àlá náà fún un:
9 “‘Bẹtiṣásárì, olórí àwọn àlùfáà onídán,+ ó dá mi lójú pé ẹ̀mí àwọn ọlọ́run mímọ́ wà nínú rẹ,+ kò sì sí àṣírí kankan tó le jù fún ọ.+ Torí náà, ṣàlàyé ìran tí mo rí lójú àlá mi fún mi àti ohun tó túmọ̀ sí.
-