Dáníẹ́lì 4:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 “‘Bẹtiṣásárì, olórí àwọn àlùfáà onídán,+ ó dá mi lójú pé ẹ̀mí àwọn ọlọ́run mímọ́ wà nínú rẹ,+ kò sì sí àṣírí kankan tó le jù fún ọ.+ Torí náà, ṣàlàyé ìran tí mo rí lójú àlá mi fún mi àti ohun tó túmọ̀ sí.
9 “‘Bẹtiṣásárì, olórí àwọn àlùfáà onídán,+ ó dá mi lójú pé ẹ̀mí àwọn ọlọ́run mímọ́ wà nínú rẹ,+ kò sì sí àṣírí kankan tó le jù fún ọ.+ Torí náà, ṣàlàyé ìran tí mo rí lójú àlá mi fún mi àti ohun tó túmọ̀ sí.