ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́sítà 8:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Torí náà, wọ́n pe àwọn akọ̀wé ọba ní àkókò yẹn ní oṣù kẹta, ìyẹn oṣù Sífánì,* ní ọjọ́ kẹtàlélógún, wọ́n sì kọ gbogbo ohun tí Módékáì pa láṣẹ fún àwọn Júù àti fún àwọn baálẹ̀,+ fún àwọn gómìnà àti àwọn ìjòyè àwọn ìpínlẹ̀*+ tó wà ní Íńdíà títí dé Etiópíà, ìpínlẹ̀ mẹ́tàdínláàádóje (127), wọ́n kọ ọ́ sí ìpínlẹ̀* kọ̀ọ̀kan ní ọ̀nà ìgbàkọ̀wé tirẹ̀ àti sí àwùjọ èèyàn kọ̀ọ̀kan ní èdè tirẹ̀, bákan náà, wọ́n kọ ọ́ sí àwọn Júù ní ọ̀nà ìgbàkọ̀wé wọn àti ní èdè wọn.

  • Dáníẹ́lì 4:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 “Ọba Nebukadinésárì kéde fún gbogbo èèyàn, orílẹ̀-èdè àti ẹ̀yà tó ń gbé ní gbogbo ayé pé: Kí àlàáfíà yín pọ̀ sí i!

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́