Dáníẹ́lì 5:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Dáríúsì + ará Mídíà sì gba ìjọba; ọjọ́ orí rẹ̀ jẹ́ nǹkan bí ọdún méjìlélọ́gọ́ta (62). Dáníẹ́lì 6:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ó dáa lójú Dáríúsì kó fi ọgọ́fà (120) baálẹ̀ jẹ lórí gbogbo ìjọba náà.+ 2 Ó fi ìjòyè mẹ́ta ṣe olórí wọn, Dáníẹ́lì+ jẹ́ ọ̀kan lára wọn; àwọn baálẹ̀+ náà á máa jábọ̀ fún wọn, kí ọba má bàa pàdánù ohunkóhun.
6 Ó dáa lójú Dáríúsì kó fi ọgọ́fà (120) baálẹ̀ jẹ lórí gbogbo ìjọba náà.+ 2 Ó fi ìjòyè mẹ́ta ṣe olórí wọn, Dáníẹ́lì+ jẹ́ ọ̀kan lára wọn; àwọn baálẹ̀+ náà á máa jábọ̀ fún wọn, kí ọba má bàa pàdánù ohunkóhun.