Dáníẹ́lì 7:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 àti nípa ìwo mẹ́wàá+ tó wà ní orí rẹ̀ àti ìwo míì tó jáde, tí mẹ́ta sì ṣubú níwájú rẹ̀,+ ìwo tó ní ojú àti ẹnu tó ń sọ àwọn ọ̀rọ̀ ìgbéraga,* tí ìrísí rẹ̀ sì tóbi ju ti àwọn yòókù. Ìfihàn 13:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ó fún un ní ẹnu tó ń sọ àwọn nǹkan ńláńlá àti ọ̀rọ̀ òdì, ó sì fún un ní àṣẹ tó máa lò fún oṣù méjìlélógójì (42).+
20 àti nípa ìwo mẹ́wàá+ tó wà ní orí rẹ̀ àti ìwo míì tó jáde, tí mẹ́ta sì ṣubú níwájú rẹ̀,+ ìwo tó ní ojú àti ẹnu tó ń sọ àwọn ọ̀rọ̀ ìgbéraga,* tí ìrísí rẹ̀ sì tóbi ju ti àwọn yòókù.
5 Ó fún un ní ẹnu tó ń sọ àwọn nǹkan ńláńlá àti ọ̀rọ̀ òdì, ó sì fún un ní àṣẹ tó máa lò fún oṣù méjìlélógójì (42).+