Dáníẹ́lì 7:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Bí mo ṣe ń ronú nípa àwọn ìwo náà, wò ó! ìwo míì tó kéré + jáde láàárín wọn, a sì fa mẹ́ta lára àwọn ìwo àkọ́kọ́ tu kúrò níwájú rẹ̀. Wò ó! ojú tó dà bíi ti èèyàn wà lára ìwo yìí, ó sì ní ẹnu tó ń sọ̀rọ̀ ìgbéraga.*+
8 Bí mo ṣe ń ronú nípa àwọn ìwo náà, wò ó! ìwo míì tó kéré + jáde láàárín wọn, a sì fa mẹ́ta lára àwọn ìwo àkọ́kọ́ tu kúrò níwájú rẹ̀. Wò ó! ojú tó dà bíi ti èèyàn wà lára ìwo yìí, ó sì ní ẹnu tó ń sọ̀rọ̀ ìgbéraga.*+