Dáníẹ́lì 7:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Àmọ́ àwọn ẹni mímọ́ ti Onípò Àjùlọ+ máa gba ìjọba,+ ìjọba náà sì máa jẹ́ tiwọn+ títí láé, àní títí láé àti láéláé.’ Dáníẹ́lì 7:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 “‘A sì fún àwọn èèyàn tó jẹ́ ẹni mímọ́ ti Onípò Àjùlọ ní ìjọba, àkóso àti títóbi àwọn ìjọba lábẹ́ gbogbo ọ̀run.+ Ìjọba tó máa wà títí láé ni ìjọba wọn,+ gbogbo ìjọba á máa sìn wọ́n, wọ́n á sì máa ṣègbọràn sí wọn.’
18 Àmọ́ àwọn ẹni mímọ́ ti Onípò Àjùlọ+ máa gba ìjọba,+ ìjọba náà sì máa jẹ́ tiwọn+ títí láé, àní títí láé àti láéláé.’
27 “‘A sì fún àwọn èèyàn tó jẹ́ ẹni mímọ́ ti Onípò Àjùlọ ní ìjọba, àkóso àti títóbi àwọn ìjọba lábẹ́ gbogbo ọ̀run.+ Ìjọba tó máa wà títí láé ni ìjọba wọn,+ gbogbo ìjọba á máa sìn wọ́n, wọ́n á sì máa ṣègbọràn sí wọn.’