Nehemáyà 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Ọ̀rọ̀ Nehemáyà*+ ọmọ Hakaláyà nìyí: Ní oṣù Kísíléfì,* ní ogún ọdún ìṣàkóso ọba,* mo wà ní Ṣúṣánì*+ ilé ńlá.* Ẹ́sítà 2:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Nígbà tí wọ́n kéde ọ̀rọ̀ ọba àti òfin rẹ̀, tí wọ́n sì kó ọ̀pọ̀ ọ̀dọ́bìnrin jọ sí Ṣúṣánì* ilé ńlá* lábẹ́ àbójútó Hégáì,+ wọ́n mú Ẹ́sítà náà wá sí ilé* ọba lábẹ́ àbójútó Hégáì, olùtọ́jú àwọn obìnrin.
1 Ọ̀rọ̀ Nehemáyà*+ ọmọ Hakaláyà nìyí: Ní oṣù Kísíléfì,* ní ogún ọdún ìṣàkóso ọba,* mo wà ní Ṣúṣánì*+ ilé ńlá.*
8 Nígbà tí wọ́n kéde ọ̀rọ̀ ọba àti òfin rẹ̀, tí wọ́n sì kó ọ̀pọ̀ ọ̀dọ́bìnrin jọ sí Ṣúṣánì* ilé ńlá* lábẹ́ àbójútó Hégáì,+ wọ́n mú Ẹ́sítà náà wá sí ilé* ọba lábẹ́ àbójútó Hégáì, olùtọ́jú àwọn obìnrin.