Ẹ́sítà 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Nígbà ayé Ahasuérúsì,* ìyẹn Ahasuérúsì tó ṣàkóso ìpínlẹ̀* mẹ́tàdínláàádóje+ (127) láti Íńdíà títí dé Etiópíà,* Ẹ́sítà 1:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 ní ọdún kẹta ìjọba rẹ̀, ó se àsè ńlá fún gbogbo àwọn ìjòyè rẹ̀ àti àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀. Àwọn ọmọ ogun Páṣíà+ àti Mídíà,+ àwọn èèyàn pàtàkì àti àwọn olórí ìpínlẹ̀* wà níwájú rẹ̀,
1 Nígbà ayé Ahasuérúsì,* ìyẹn Ahasuérúsì tó ṣàkóso ìpínlẹ̀* mẹ́tàdínláàádóje+ (127) láti Íńdíà títí dé Etiópíà,*
3 ní ọdún kẹta ìjọba rẹ̀, ó se àsè ńlá fún gbogbo àwọn ìjòyè rẹ̀ àti àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀. Àwọn ọmọ ogun Páṣíà+ àti Mídíà,+ àwọn èèyàn pàtàkì àti àwọn olórí ìpínlẹ̀* wà níwájú rẹ̀,