ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 2:7, 8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Jèhófà ń sọni di aláìní, ó sì ń sọni di ọlọ́rọ̀;+

      Ó ń rẹni wálẹ̀, ó sì ń gbéni ga.+

       8 Ó ń gbé aláìní dìde látinú eruku;

      Ó ń gbé tálákà dìde látinú eérú,*+

      Láti mú kí wọ́n jókòó pẹ̀lú àwọn olórí,

      Ó fún wọn ní ìjókòó iyì.

      Ti Jèhófà ni àwọn ìpìlẹ̀ ayé,+

      Ó sì gbé ilẹ̀ tó ń mú èso jáde ka orí wọn.

  • Sáàmù 75:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Nítorí Ọlọ́run jẹ́ onídàájọ́.+

      Á rẹ ẹnì kan wálẹ̀, á sì gbé ẹlòmíì ga.+

  • Jeremáyà 27:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 ‘Èmi ni mo dá ayé, èèyàn àti ẹranko tó wà lórí ilẹ̀ nípa agbára ńlá mi àti nípa apá mi tí mo nà jáde, mo sì ti fún ẹni tí mo fẹ́.*+

  • Dáníẹ́lì 4:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Àṣẹ tí àwọn olùṣọ́+ pa nìyí, àwọn ẹni mímọ́ ló sì béèrè fún un, kí àwọn èèyàn tó wà láàyè lè mọ̀ pé Ẹni Gíga Jù Lọ ni Alákòóso nínú ìjọba aráyé,+ ẹni tó bá wù ú ló ń gbé e fún, ẹni tó sì rẹlẹ̀ jù nínú àwọn èèyàn ló ń fi síbẹ̀.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́