Ìdárò 2:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Jèhófà ti ṣe ohun tó ní lọ́kàn;+ ó ti ṣe ohun tó sọ,+Ohun tó ti pa láṣẹ tipẹ́tipẹ́.+ Ó ti ya ọ́ lulẹ̀, kò sì ṣàánú rẹ.+ Ó ti mú kí ọ̀tá yọ̀ lórí rẹ; ó ti mú kí agbára* àwọn elénìní rẹ borí.
17 Jèhófà ti ṣe ohun tó ní lọ́kàn;+ ó ti ṣe ohun tó sọ,+Ohun tó ti pa láṣẹ tipẹ́tipẹ́.+ Ó ti ya ọ́ lulẹ̀, kò sì ṣàánú rẹ.+ Ó ti mú kí ọ̀tá yọ̀ lórí rẹ; ó ti mú kí agbára* àwọn elénìní rẹ borí.