ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 79:8, 9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Má ṣe ka ẹ̀ṣẹ̀ àwọn baba ńlá wa sí wa lọ́rùn.+

      Tètè wá ṣàánú wa,+

      Torí wọ́n ti bá wa kanlẹ̀.

       9 Ràn wá lọ́wọ́, Ọlọ́run ìgbàlà wa,+

      Nítorí orúkọ rẹ ológo;

      Gbà wá sílẹ̀, kí o sì dárí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa jì wá* nítorí orúkọ rẹ.+

  • Àìsáyà 63:18, 19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Ó jẹ́ ti àwọn èèyàn mímọ́ rẹ fúngbà díẹ̀.

      Àwọn ọ̀tá wa ti tẹ ibi mímọ́ rẹ mọ́lẹ̀.+

      19 Ó pẹ́ gan-an tí a ti dà bí àwọn tí o kò ṣàkóso wọn rí,

      Bí àwọn tí a ò fi orúkọ rẹ pè rí.

  • Jeremáyà 14:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Kí nìdí tí o fi dà bí ọkùnrin tí nǹkan tojú sú,

      Bí alágbára ọkùnrin tí kò lè gbani là?

      Nítorí o wà láàárín wa, Jèhófà,+

      Wọ́n sì ń fi orúkọ rẹ pè wá.+

      Má fi wá sílẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́