Nehemáyà 11:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àwọn olórí àwọn èèyàn náà ń gbé ní Jerúsálẹ́mù;+ àmọ́ ìyókù àwọn èèyàn náà ṣẹ́ kèké+ láti mú ẹnì kan nínú èèyàn mẹ́wàá láti lọ máa gbé ní Jerúsálẹ́mù, ìlú mímọ́, nígbà tí àwọn mẹ́sàn-án yòókù á máa gbé ní àwọn ìlú míì. Àìsáyà 52:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 52 Jí! Jí! Gbé agbára wọ̀,+ ìwọ Síónì!+ Wọ aṣọ rẹ tó rẹwà,+ ìwọ Jerúsálẹ́mù, ìlú mímọ́! Torí ẹni tí kò dádọ̀dọ́* àti aláìmọ́ kò ní wọ inú rẹ mọ́.+
11 Àwọn olórí àwọn èèyàn náà ń gbé ní Jerúsálẹ́mù;+ àmọ́ ìyókù àwọn èèyàn náà ṣẹ́ kèké+ láti mú ẹnì kan nínú èèyàn mẹ́wàá láti lọ máa gbé ní Jerúsálẹ́mù, ìlú mímọ́, nígbà tí àwọn mẹ́sàn-án yòókù á máa gbé ní àwọn ìlú míì.
52 Jí! Jí! Gbé agbára wọ̀,+ ìwọ Síónì!+ Wọ aṣọ rẹ tó rẹwà,+ ìwọ Jerúsálẹ́mù, ìlú mímọ́! Torí ẹni tí kò dádọ̀dọ́* àti aláìmọ́ kò ní wọ inú rẹ mọ́.+