Sáàmù 36:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ọ̀dọ̀ rẹ ni orísun ìyè wà;+Ipasẹ̀ ìmọ́lẹ̀ rẹ ni a fi lè rí ìmọ́lẹ̀.+ Sáàmù 112:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nínú òkùnkùn, ó ń tàn yanran bí ìmọ́lẹ̀ sí àwọn adúróṣinṣin.+ ח [Hétì] Ó jẹ́ agbatẹnirò* àti aláàánú+ àti olódodo.
4 Nínú òkùnkùn, ó ń tàn yanran bí ìmọ́lẹ̀ sí àwọn adúróṣinṣin.+ ח [Hétì] Ó jẹ́ agbatẹnirò* àti aláàánú+ àti olódodo.