Dáníẹ́lì 8:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Òbúkọ onírun náà dúró fún ọba ilẹ̀ Gíríìsì;+ ìwo ńlá tó wà láàárín àwọn ojú rẹ̀ sì dúró fún ọba àkọ́kọ́.+
21 Òbúkọ onírun náà dúró fún ọba ilẹ̀ Gíríìsì;+ ìwo ńlá tó wà láàárín àwọn ojú rẹ̀ sì dúró fún ọba àkọ́kọ́.+