-
Jẹ́nẹ́sísì 41:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Fáráò sọ fún Jósẹ́fù pé: “Mo lá àlá kan, àmọ́ kò sẹ́ni tó lè túmọ̀ rẹ̀. Ṣùgbọ́n mo ti gbọ́ pé tí wọ́n bá rọ́ àlá fún ọ, o lè túmọ̀ rẹ̀.”+
-