-
Ìfihàn 4:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Nígbàkigbà tí àwọn ẹ̀dá alààyè náà bá fi ògo àti ọlá fún Ẹni tó jókòó lórí ìtẹ́, Ẹni tó wà láàyè títí láé àti láéláé,+ tí wọ́n sì dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ̀,
-