Dáníẹ́lì 8:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ó máa lágbára gan-an, àmọ́ kì í ṣe nípa agbára òun fúnra rẹ̀. Ó máa mú ìparun wá lọ́nà tó ṣàrà ọ̀tọ̀,* ó máa ṣàṣeyọrí, ó sì máa ṣe ohun tó gbéṣẹ́. Ó máa pa àwọn alágbára run àti àwọn tó jẹ́ ẹni mímọ́.+
24 Ó máa lágbára gan-an, àmọ́ kì í ṣe nípa agbára òun fúnra rẹ̀. Ó máa mú ìparun wá lọ́nà tó ṣàrà ọ̀tọ̀,* ó máa ṣàṣeyọrí, ó sì máa ṣe ohun tó gbéṣẹ́. Ó máa pa àwọn alágbára run àti àwọn tó jẹ́ ẹni mímọ́.+