-
Dáníẹ́lì 4:20-22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 “‘Igi tí o rí, tó di ńlá, tó sì lágbára, tí orí rẹ̀ kan ọ̀run, tí gbogbo ayé sì ń rí i,+ 21 tí àwọn ewé rẹ̀ rẹwà, tí èso rẹ̀ pọ̀ yanturu, tó sì jẹ́ oúnjẹ fún gbogbo ayé, tí àwọn ẹranko orí ilẹ̀ ń gbé lábẹ́ rẹ̀, tí àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run sì ń gbé lórí àwọn ẹ̀ka rẹ̀,+ 22 ọba, ìwọ ni, torí pé o ti di ẹni ńlá, o sì ti di alágbára, títóbi rẹ ti dé ọ̀run,+ àkóso rẹ sì ti dé àwọn ìkángun ayé.+
-