Dáníẹ́lì 4:10, 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 “‘Nínú ìran tí mo rí nígbà tí mo wà lórí ibùsùn mi, mo rí igi kan+ ní àárín ayé, igi náà sì ga fíofío.+ 11 Igi náà dàgbà, ó sì lágbára, orí rẹ̀ kan ọ̀run, a sì lè rí i láti gbogbo ìkángun ayé.
10 “‘Nínú ìran tí mo rí nígbà tí mo wà lórí ibùsùn mi, mo rí igi kan+ ní àárín ayé, igi náà sì ga fíofío.+ 11 Igi náà dàgbà, ó sì lágbára, orí rẹ̀ kan ọ̀run, a sì lè rí i láti gbogbo ìkángun ayé.