1 Àwọn Ọba 13:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Ẹ̀ṣẹ̀ agbo ilé Jèróbóámù+ yìí ló yọrí sí ìparun wọn, tí wọ́n sì pa rẹ́ kúrò lórí ilẹ̀.+