1 Àwọn Ọba 18:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ní báyìí, pe gbogbo Ísírẹ́lì jọ sọ́dọ̀ mi lórí Òkè Kámẹ́lì+ àti ọgọ́rùn-ún mẹ́rin ó lé àádọ́ta (450) wòlíì Báálì àti ọgọ́rùn-ún mẹ́rin (400) wòlíì òpó òrìṣà,*+ tó ń jẹun lórí tábìlì Jésíbẹ́lì.”
19 Ní báyìí, pe gbogbo Ísírẹ́lì jọ sọ́dọ̀ mi lórí Òkè Kámẹ́lì+ àti ọgọ́rùn-ún mẹ́rin ó lé àádọ́ta (450) wòlíì Báálì àti ọgọ́rùn-ún mẹ́rin (400) wòlíì òpó òrìṣà,*+ tó ń jẹun lórí tábìlì Jésíbẹ́lì.”