-
Sáàmù 50:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Ẹ jọ̀wọ́, ẹ rò ó wò ná, ẹ̀yin tí ẹ gbàgbé Ọlọ́run,+
Kí n má bàa fà yín ya pẹ́rẹpẹ̀rẹ láìsí ẹni tó máa gbà yín sílẹ̀.
-
-
Hósíà 5:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Màá dà bí ọmọ kìnnìún sí Éfúrémù
Àti bíi kìnnìún* alágbára sí ilé Júdà.
-