Àìsáyà 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Ìran tí Àìsáyà*+ ọmọ Émọ́ọ̀sì rí nípa Júdà àti Jerúsálẹ́mù láyé ìgbà Ùsáyà,+ Jótámù,+ Áhásì+ àti Hẹsikáyà,+ àwọn ọba Júdà:+ Míkà 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Ọ̀rọ̀ tí Jèhófà sọ fún Míkà*+ ará Móréṣétì, nínú ìran tó rí nípa Samáríà àti Jerúsálẹ́mù láyé ìgbà Jótámù,+ Áhásì+ àti Hẹsikáyà,+ tí wọ́n jẹ́ ọba Júdà:+
1 Ìran tí Àìsáyà*+ ọmọ Émọ́ọ̀sì rí nípa Júdà àti Jerúsálẹ́mù láyé ìgbà Ùsáyà,+ Jótámù,+ Áhásì+ àti Hẹsikáyà,+ àwọn ọba Júdà:+
1 Ọ̀rọ̀ tí Jèhófà sọ fún Míkà*+ ará Móréṣétì, nínú ìran tó rí nípa Samáríà àti Jerúsálẹ́mù láyé ìgbà Jótámù,+ Áhásì+ àti Hẹsikáyà,+ tí wọ́n jẹ́ ọba Júdà:+