-
2 Kíróníkà 20:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Lákòókò yìí, gbogbo àwọn tó wá láti Júdà dúró níwájú Jèhófà, títí kan àwọn ìyàwó wọn àti àwọn ọmọ* wọn pẹ̀lú àwọn ọmọ wọn kéékèèké.
-