Ìsíkíẹ́lì 34:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Àwọn igi oko yóò so èso, ilẹ̀ yóò mú èso jáde,+ wọn yóò sì máa gbé láìséwu lórí ilẹ̀ náà. Wọ́n á sì wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà tí mo bá ṣẹ́ àwọn ọ̀pá àjàgà wọn,+ tí mo sì gbà wọ́n sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn tó fi wọ́n ṣẹrú.
27 Àwọn igi oko yóò so èso, ilẹ̀ yóò mú èso jáde,+ wọn yóò sì máa gbé láìséwu lórí ilẹ̀ náà. Wọ́n á sì wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà tí mo bá ṣẹ́ àwọn ọ̀pá àjàgà wọn,+ tí mo sì gbà wọ́n sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn tó fi wọ́n ṣẹrú.