Léfítíkù 26:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 èmi yóò rọ ọ̀wààrà òjò fún yín ní àkókò tó yẹ,+ ilẹ̀ yóò mú èso jáde,+ àwọn igi oko yóò sì so èso. Sáàmù 85:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Bẹ́ẹ̀ ni, Jèhófà yóò pèsè ohun rere,*+Ilẹ̀ wa yóò sì máa mú èso jáde.+ Àìsáyà 35:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ó dájú pé ó máa yọ ìtànná;+Ó máa yọ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀, ó sì máa kígbe ayọ̀. A máa fún un ní ògo Lẹ́bánónì,+Ẹwà Kámẹ́lì+ àti ti Ṣárónì.+ Wọ́n máa rí ògo Jèhófà, ẹwà Ọlọ́run wa. Ìsíkíẹ́lì 36:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Èmi yóò mú kí èso igi àti irè oko pọ̀ jaburata, kí ojú má bàa tì yín mọ́ láàárín àwọn orílẹ̀-èdè torí ìyàn.+
2 Ó dájú pé ó máa yọ ìtànná;+Ó máa yọ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀, ó sì máa kígbe ayọ̀. A máa fún un ní ògo Lẹ́bánónì,+Ẹwà Kámẹ́lì+ àti ti Ṣárónì.+ Wọ́n máa rí ògo Jèhófà, ẹwà Ọlọ́run wa.
30 Èmi yóò mú kí èso igi àti irè oko pọ̀ jaburata, kí ojú má bàa tì yín mọ́ láàárín àwọn orílẹ̀-èdè torí ìyàn.+