Émọ́sì 9:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Màá kó àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì tó wà ní ìgbèkùn pa dà,+Wọ́n á tún àwọn ìlú tó ti di ahoro kọ́, wọ́n á sì máa gbé inú wọn;+Wọ́n á gbin ọgbà àjàrà, wọ́n á sì mu wáìnì wọn,+Wọ́n á ṣe ọgbà, wọ́n á sì jẹ èso wọn.’+ Sekaráyà 8:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Torí èso tí wọ́n máa gbìn yóò mú àlàáfíà wá; àjàrà yóò so èso, ilẹ̀ yóò mú èso rẹ̀ jáde,+ ọ̀run yóò sẹ ìrì; èmi yóò sì mú kí àwọn tó ṣẹ́ kù lára àwọn èèyàn yìí jogún gbogbo nǹkan yìí.+
14 Màá kó àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì tó wà ní ìgbèkùn pa dà,+Wọ́n á tún àwọn ìlú tó ti di ahoro kọ́, wọ́n á sì máa gbé inú wọn;+Wọ́n á gbin ọgbà àjàrà, wọ́n á sì mu wáìnì wọn,+Wọ́n á ṣe ọgbà, wọ́n á sì jẹ èso wọn.’+
12 Torí èso tí wọ́n máa gbìn yóò mú àlàáfíà wá; àjàrà yóò so èso, ilẹ̀ yóò mú èso rẹ̀ jáde,+ ọ̀run yóò sẹ ìrì; èmi yóò sì mú kí àwọn tó ṣẹ́ kù lára àwọn èèyàn yìí jogún gbogbo nǹkan yìí.+