Àìsáyà 35:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àwọn tí Jèhófà rà pa dà máa pa dà wá,+ wọ́n sì máa kígbe ayọ̀ wá sí Síónì.+ Ayọ̀ tí kò lópin máa dé orí wọn ládé.+ Wọ́n á máa yọ̀ gidigidi, inú wọn á sì máa dùn,Ẹ̀dùn ọkàn àti ìbànújẹ́ kò ní sí mọ́.+ Àìsáyà 61:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Dípò ìtìjú, ẹ máa ní ìpín ìlọ́po méjì,Dípò ìdójútì, wọ́n máa kígbe ayọ̀ nítorí ìpín wọn. Àní, ìpín ìlọ́po méjì ni wọ́n máa gbà ní ilẹ̀ wọn.+ Wọ́n á máa yọ̀ títí ayérayé.+
10 Àwọn tí Jèhófà rà pa dà máa pa dà wá,+ wọ́n sì máa kígbe ayọ̀ wá sí Síónì.+ Ayọ̀ tí kò lópin máa dé orí wọn ládé.+ Wọ́n á máa yọ̀ gidigidi, inú wọn á sì máa dùn,Ẹ̀dùn ọkàn àti ìbànújẹ́ kò ní sí mọ́.+
7 Dípò ìtìjú, ẹ máa ní ìpín ìlọ́po méjì,Dípò ìdójútì, wọ́n máa kígbe ayọ̀ nítorí ìpín wọn. Àní, ìpín ìlọ́po méjì ni wọ́n máa gbà ní ilẹ̀ wọn.+ Wọ́n á máa yọ̀ títí ayérayé.+