Ọbadáyà 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ní ọjọ́ tí ìwọ ta kété sí ẹ̀gbẹ́ kan,Ní ọjọ́ tí àwọn àjèjì mú àwọn ọmọ ogun rẹ̀ lẹ́rú,+Nígbà tí àwọn àjèjì gba ẹnubodè rẹ̀ wọlé, tí wọ́n sì ṣẹ́ kèké+ lórí Jerúsálẹ́mù,Ìwọ náà ṣe bíi tiwọn.
11 Ní ọjọ́ tí ìwọ ta kété sí ẹ̀gbẹ́ kan,Ní ọjọ́ tí àwọn àjèjì mú àwọn ọmọ ogun rẹ̀ lẹ́rú,+Nígbà tí àwọn àjèjì gba ẹnubodè rẹ̀ wọlé, tí wọ́n sì ṣẹ́ kèké+ lórí Jerúsálẹ́mù,Ìwọ náà ṣe bíi tiwọn.