Sáàmù 136:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 136 Ẹ fi ọpẹ́ fún Jèhófà, nítorí ó jẹ́ ẹni rere;+Ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.+ Mátíù 19:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ó sọ fún un pé: “Kí ló dé tí o fi ń bi mí nípa ohun rere? Ẹni rere kan ló wà.+ Àmọ́ o, tí o bá fẹ́ jogún ìyè, máa pa àwọn àṣẹ mọ́ nígbà gbogbo.”+
17 Ó sọ fún un pé: “Kí ló dé tí o fi ń bi mí nípa ohun rere? Ẹni rere kan ló wà.+ Àmọ́ o, tí o bá fẹ́ jogún ìyè, máa pa àwọn àṣẹ mọ́ nígbà gbogbo.”+