Jóòbù 9:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ọlọ́gbọ́n ni,* ó sì ní agbára gan-an.+ Ta ló lè ta kò ó, tí kò ní fara pa?+