-
Dáníẹ́lì 5:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Àmọ́ nígbà tí ọkàn rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí í gbéra ga, tí ẹ̀mí rẹ̀ sì le, débi tó fi kọjá àyè rẹ̀,+ a rẹ̀ ẹ́ wálẹ̀ látorí ìtẹ́ ìjọba rẹ̀, a sì gba iyì rẹ̀ kúrò lọ́wọ́ rẹ̀.
-
-
Róòmù 2:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Àmọ́ nítorí agídí rẹ àti ọkàn rẹ tí kò ronú pìwà dà, ò ń kó ìrunú jọ sórí ara rẹ, ìrunú yìí máa hàn ní ọjọ́ ìdájọ́ òdodo Ọlọ́run.+
-