ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Òwe 11:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Ọrọ̀* kò ní ṣeni láǹfààní ní ọjọ́ ìbínú ńlá,+

      Àmọ́ òdodo ló ń gbani lọ́wọ́ ikú.+

  • Àìsáyà 2:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Ní ọjọ́ yẹn, àwọn èèyàn máa mú àwọn ọlọ́run wọn tí kò ní láárí, tí wọ́n fi fàdákà àti wúrà ṣe,

      Èyí tí wọ́n ṣe fúnra wọn kí wọ́n lè máa forí balẹ̀ fún un,

      Wọ́n á sì jù wọ́n sí àwọn asín* àti àwọn àdán,+

  • Ìsíkíẹ́lì 7:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 “‘Wọ́n á ju fàdákà wọn sí ojú ọ̀nà, wúrà wọn á sì di ohun ìríra lójú wọn. Fàdákà wọn tàbí wúrà wọn kò ní lè gbà wọ́n là ní ọjọ́ ìbínú Jèhófà.+ Kò ní tẹ́ wọn* lọ́rùn, wọn ò sì ní yó, torí ó* ti di ohun ìkọ̀sẹ̀ tó ń mú kí wọ́n ṣe àṣìṣe.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́