-
Ẹ́sírà 4:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Lẹ́yìn tí wọ́n ka ẹ̀dà ìwé àṣẹ Ọba Atasásítà níwájú Réhúmù àti Ṣímúṣáì akọ̀wé òfin pẹ̀lú àwọn ẹlẹgbẹ́ wọn, lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, wọ́n lọ sí Jerúsálẹ́mù lọ́dọ̀ àwọn Júù, wọ́n sì fipá dá wọn dúró.
-