Jeremáyà 50:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Màá mú Ísírẹ́lì pa dà sí ibi ìjẹko rẹ̀,+ á jẹko ní Kámẹ́lì àti ní Báṣánì,+ á* sì ní ìtẹ́lọ́rùn lórí àwọn òkè Éfúrémù+ àti ti Gílíádì.’”+ Míkà 7:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Fi ọ̀pá rẹ ṣe olùṣọ́ àgùntàn àwọn èèyàn rẹ, agbo ẹran tó jẹ́ ogún rẹ,+Tó ń dá gbé inú igbó, láàárín ọgbà eléso. Jẹ́ kí Báṣánì àti Gílíádì+ fún wọn ní oúnjẹ bíi ti àtijọ́.
19 Màá mú Ísírẹ́lì pa dà sí ibi ìjẹko rẹ̀,+ á jẹko ní Kámẹ́lì àti ní Báṣánì,+ á* sì ní ìtẹ́lọ́rùn lórí àwọn òkè Éfúrémù+ àti ti Gílíádì.’”+
14 Fi ọ̀pá rẹ ṣe olùṣọ́ àgùntàn àwọn èèyàn rẹ, agbo ẹran tó jẹ́ ogún rẹ,+Tó ń dá gbé inú igbó, láàárín ọgbà eléso. Jẹ́ kí Báṣánì àti Gílíádì+ fún wọn ní oúnjẹ bíi ti àtijọ́.