Àìsáyà 11:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ó máa gbé àmì* kan sókè fún àwọn orílẹ̀-èdè, ó sì máa kó àwọn tó fọ́n ká lára Ísírẹ́lì jọ,+ ó máa kó àwọn tó tú ká lára Júdà jọ láti ìkángun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin ayé.+ Àìsáyà 11:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ọ̀nà kan sì máa jáde+ láti Ásíríà fún àṣẹ́kù àwọn èèyàn rẹ̀ yòókù,+Bó ṣe rí fún Ísírẹ́lì ní ọjọ́ tó kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.
12 Ó máa gbé àmì* kan sókè fún àwọn orílẹ̀-èdè, ó sì máa kó àwọn tó fọ́n ká lára Ísírẹ́lì jọ,+ ó máa kó àwọn tó tú ká lára Júdà jọ láti ìkángun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin ayé.+
16 Ọ̀nà kan sì máa jáde+ láti Ásíríà fún àṣẹ́kù àwọn èèyàn rẹ̀ yòókù,+Bó ṣe rí fún Ísírẹ́lì ní ọjọ́ tó kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.