2 Kíróníkà 6:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ṣùgbọ́n mo ti yan Jerúsálẹ́mù+ kí orúkọ mi lè máa wà níbẹ̀, mo sì ti yan Dáfídì láti ṣe olórí àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì.’+ Sekaráyà 1:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 “Kéde lẹ́ẹ̀kan sí i pé, ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Ìwà rere máa pa dà kún àkúnwọ́sílẹ̀ ní àwọn ìlú mi; Jèhófà yóò sì pa dà tu Síónì nínú,+ yóò sì tún Jerúsálẹ́mù yàn.”’”+
6 Ṣùgbọ́n mo ti yan Jerúsálẹ́mù+ kí orúkọ mi lè máa wà níbẹ̀, mo sì ti yan Dáfídì láti ṣe olórí àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì.’+
17 “Kéde lẹ́ẹ̀kan sí i pé, ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Ìwà rere máa pa dà kún àkúnwọ́sílẹ̀ ní àwọn ìlú mi; Jèhófà yóò sì pa dà tu Síónì nínú,+ yóò sì tún Jerúsálẹ́mù yàn.”’”+