-
Diutarónómì 28:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 “Jèhófà máa mú kí ègún bá ọ, kí nǹkan dà rú fún ọ, kí ìyà sì jẹ ọ́ nínú gbogbo ohun tí o bá dáwọ́ lé títí o fi máa pa run, tí o sì máa yára ṣègbé, torí ìwà búburú tí ò ń hù àti torí pé o pa mí tì.+
-
-
Jeremáyà 23:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Ìbínú Jèhófà kò ní dáwọ́ dúró
Títí á fi ṣe ohun tó wà lọ́kàn rẹ̀, tí á sì mú èrò rẹ̀ ṣẹ.
Ní àkókò òpin, ọ̀rọ̀ yìí á yé yín dáadáa.
-