Àìsáyà 1:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “Àǹfààní wo ni ọ̀pọ̀ ẹbọ yín ń ṣe mí?”+ ni Jèhófà wí. “Àwọn ẹbọ sísun yín tí ẹ fi àgbò+ ṣe àti ọ̀rá àwọn ẹran tí ẹ bọ́ dáadáa + ti sú mi,Inú mi ò dùn sí ẹ̀jẹ̀+ àwọn akọ ọmọ màlúù,+ ọ̀dọ́ àgùntàn àti ewúrẹ́.+ Jeremáyà 6:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 “Kò já mọ́ nǹkan kan lójú mi pé ẹ̀ ń mú oje igi tùràrí wá láti ṢébàÀti pòròpórò olóòórùn dídùn* láti ilẹ̀ tó jìnnà. Àwọn odindi ẹbọ sísun yín kò ní ìtẹ́wọ́gbà,Àwọn ẹbọ yín kò sì mú inú mi dùn.”+
11 “Àǹfààní wo ni ọ̀pọ̀ ẹbọ yín ń ṣe mí?”+ ni Jèhófà wí. “Àwọn ẹbọ sísun yín tí ẹ fi àgbò+ ṣe àti ọ̀rá àwọn ẹran tí ẹ bọ́ dáadáa + ti sú mi,Inú mi ò dùn sí ẹ̀jẹ̀+ àwọn akọ ọmọ màlúù,+ ọ̀dọ́ àgùntàn àti ewúrẹ́.+
20 “Kò já mọ́ nǹkan kan lójú mi pé ẹ̀ ń mú oje igi tùràrí wá láti ṢébàÀti pòròpórò olóòórùn dídùn* láti ilẹ̀ tó jìnnà. Àwọn odindi ẹbọ sísun yín kò ní ìtẹ́wọ́gbà,Àwọn ẹbọ yín kò sì mú inú mi dùn.”+