-
Mátíù 9:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Ó wá fọwọ́ kan ojú wọn,+ ó sọ pé: “Kó rí bẹ́ẹ̀ fún yín gẹ́gẹ́ bí ìgbàgbọ́ yín.”
-
-
Mátíù 15:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Jésù wá dá a lóhùn pé: “Ìwọ obìnrin yìí, ìgbàgbọ́ rẹ lágbára gan-an; kó ṣẹlẹ̀ sí ọ bí o ṣe fẹ́.” Ara ọmọbìnrin rẹ̀ sì yá láti wákàtí yẹn lọ.
-
-
Máàkù 9:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Jésù sọ fún un pé: “Kì í ṣe ọ̀rọ̀, ‘Tí o bá lè’! Ó dájú pé ohun gbogbo ṣeé ṣe fún ẹni tó bá ní ìgbàgbọ́.”+
-