Lúùkù 16:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “Òfin àti àwọn Wòlíì wà títí dìgbà Jòhánù. Látìgbà yẹn lọ, à ń kéde Ìjọba Ọlọ́run gẹ́gẹ́ bí ìhìn rere, onírúurú èèyàn sì ń fi agbára lépa rẹ̀.+
16 “Òfin àti àwọn Wòlíì wà títí dìgbà Jòhánù. Látìgbà yẹn lọ, à ń kéde Ìjọba Ọlọ́run gẹ́gẹ́ bí ìhìn rere, onírúurú èèyàn sì ń fi agbára lépa rẹ̀.+