Mátíù 11:12, 13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Láti àwọn ọjọ́ Jòhánù Arinibọmi títí di báyìí, Ìjọba ọ̀run ni ohun tí àwọn èèyàn ń fi agbára lépa, ọwọ́ àwọn tó ń sapá gidigidi sì ń tẹ̀ ẹ́.+ 13 Torí pé gbogbo wọn, àwọn Wòlíì àti Òfin, sọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ títí dìgbà Jòhánù;+
12 Láti àwọn ọjọ́ Jòhánù Arinibọmi títí di báyìí, Ìjọba ọ̀run ni ohun tí àwọn èèyàn ń fi agbára lépa, ọwọ́ àwọn tó ń sapá gidigidi sì ń tẹ̀ ẹ́.+ 13 Torí pé gbogbo wọn, àwọn Wòlíì àti Òfin, sọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ títí dìgbà Jòhánù;+