Máàkù 8:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Àní, gbangba ló ti ń sọ ọ̀rọ̀ yẹn. Àmọ́ Pétérù mú un lọ sí ẹ̀gbẹ́ kan, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í bá a wí.+