Mátíù 16:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ni Pétérù bá mú un lọ sí ẹ̀gbẹ́ kan, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í bá a wí, ó sọ pé: “Ṣàánú ara rẹ, Olúwa; èyí ò ní ṣẹlẹ̀ sí ọ rárá.”+
22 Ni Pétérù bá mú un lọ sí ẹ̀gbẹ́ kan, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í bá a wí, ó sọ pé: “Ṣàánú ara rẹ, Olúwa; èyí ò ní ṣẹlẹ̀ sí ọ rárá.”+