Lúùkù 20:35, 36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 àmọ́ àwọn tí a ti kà yẹ pé kí wọ́n jèrè ètò àwọn nǹkan yẹn àti àjíǹde òkú kì í gbéyàwó, a kì í sì í fà wọ́n fún ọkọ.+ 36 Kódà, wọn ò lè kú mọ́, torí wọ́n dà bí àwọn áńgẹ́lì, ọmọ Ọlọ́run sì ni wọ́n ní ti pé wọ́n jẹ́ àwọn ọmọ àjíǹde.
35 àmọ́ àwọn tí a ti kà yẹ pé kí wọ́n jèrè ètò àwọn nǹkan yẹn àti àjíǹde òkú kì í gbéyàwó, a kì í sì í fà wọ́n fún ọkọ.+ 36 Kódà, wọn ò lè kú mọ́, torí wọ́n dà bí àwọn áńgẹ́lì, ọmọ Ọlọ́run sì ni wọ́n ní ti pé wọ́n jẹ́ àwọn ọmọ àjíǹde.