-
Máàkù 7:3, 4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 (Torí àwọn Farisí àti gbogbo àwọn Júù kì í jẹun láìwẹ ọwọ́ wọn títí dé ìgúnpá, wọ́n rin kinkin mọ́ àṣà àtọwọ́dọ́wọ́ àwọn èèyàn àtijọ́, 4 tí wọ́n bá sì ti ọjà dé, wọn kì í jẹun àfi tí wọ́n bá wẹ ara wọn. Ọ̀pọ̀ àṣà àtọwọ́dọ́wọ́ míì wà tí wọ́n gbà, tí wọ́n sì rin kinkin mọ́, irú bí ìbatisí àwọn ife, ṣágo àti àwọn ohun èlò tí wọ́n fi bàbà ṣe.)+
-